10.9.16

ÌWÉ ÌTUNMỌ̀

Òyìnbó: Ìtunmọ̀
1. coconut: àgbon

2. ailment: àìsàn; àrùn

3. colour: Àwọ̀

4. explanation: Àlàyé

5. goat: Ewúrẹ́

6. medicine: Egbòogi

7. wood: Igi

8. voyage: Àjò; ìrìn-àjò

9. snake: Ejò

10. looking-glass: dígí

No comments:

Post a Comment