4.9.16

Òrò ìsíjú fun ÒròYorùbá

Òrò Yorùbá dé, kí eku ilé gbó, kó so fún t'oko, kí àdán gbo, kó rò fún òòbè.

Òrò Yorùbá: fún ìgbé láruge èdè, ìse, àsà àti lítírésò Yorùbá.

Yorùbá ìjìnlè,  Yorùbá tiwa-n-tiwa.

K'óòótù ò jíire.



Ire kàbìtì ..

No comments:

Post a Comment