5.10.16

ÀWỌN ỌBA ALAYÉ

ÌPÍNLẸ̀ ÒGÙN

ORÚKỌ OYÈ ORÚKỌ ÌLÚ

1. Aláké Abẹ́òkúta

2. Ọlọ́tà Ọ̀tà

3. Awùjalẹ̀ Ìjẹ̀bú Òde

4. Orímọlúsì Ìjẹ̀bú Igbó

5. Àkárìgbò Rẹ́mọ

6. Ọdẹmọ Ìṣarà

7. Olú Ìlaròó

8. Aláyé Ayétòrò

9. Olówu Òwu

10. Ọbaládí Afọn

11. Moloda Odògbólú

12. Ológèrè Ògèrè

13. Alápẹ́ru Ìpẹru

14. Ọlọ́fin Ìliṣàn Rẹ́mọ

15. Olúgbolú Ìta Ògbólú

16. Olúbarà Ìbarà(Abẹ́òkúta)

17. Ọlọ́fin Adó Odò (Ẹ̀gbádò)

No comments:

Post a Comment