OBA AKIOLU PE AADORIN LE META ODUN L'OKE EEPE
A ki Oba Rilwan Babatunde Osuolale Aremu Akiolu 1, Oba Ilu Eko pe won ku ayeye odun keta le l'aadorin ti won ti wa loke eepe. A ki Oba Eko ni ojo kokan din l'ogbon osu Owara, Odun 1943.
Oba Akiolu ni Oba ikokan le logun ti yoo je l'Eko Adele.
A ki Oba pe Igba Odun, odun kan ni.
No comments:
Post a Comment