13.10.16

ÌṢÍ NI L'ÉTÍ

EKO NIPA IBO'WOFUN ATI TITO OMO S'ONAN TI O DARA.

Yoruba bo wonni obinrin so'wanu...o ni oun ko lori oko..
Iwo gegebi obinrin ti oko fi gbogbo nkan te o lorun,ti oko di dindinrin patapata fun e nitori ife tinutinu ti o ni si ọ,ti iwo naa waa so ara re di alase ninu ile ti o npa ase waa..

Hmm..!

Nje iwo lee gba ki iyawo omo re naa maa se eyi pelu omo re okunrin bi..?

Eyin gegebi obi omo..

Nje e nfi eko bi a se nki'nin ko awon omo yin okunrin ati obinrin bii..?

Ni aye ode oni..kinni nkanti o fa a ti awon iyawo awa ewe ode oni kii fe ba iya oko won gbe inu ile kannaa papo?

Nje ese(sin) wa ninu wipe ki awa okunrin ati awon obinrin dijofi bi a se ni ife araawa to han araawa tan yannyan bi..?

E jeki a dijogbe awon ibeere yi yewo laarin araawa...

- Olújídé Bámijí

No comments:

Post a Comment