ÀWỌN ÌBÉÈRÈ TÓ TA KÓKÓ
1. Kíni 'Òkú ewúrẹ́ tí í fọhùn bí ènìyàn'
2. Kíni Yorùbá ṣe ń kí èèyàn báyìí: 'Ẹ kú arógun'
3. Ibo ni 'Ìgẹ̀' wà ní ààgọ̀ ara?
4. Tani olórí 'Ẹgbẹ́ Onímọ̀ Èdè Yorùbá?'
5. Tani Yorùbá máa ń kí báyìí 'Ẹ rìn wá'?
Eku ise takun takun. Ede yoruba dun. Ori buloogu yi nikan ni mo ti ni anfani lati ka ede yoruba. Esee pupo
ReplyDeleteA dupe lowo Olorun. Ipenija naa lo mu mi bere buloogu yii lati polongo Yoruba lori itakun agbaye, intaneeti. Orisirisi isori ni awon ohun ti a n ko wa, bee a si n meye bo lapo ni. N je e ti wo awon isori miiran bi?
ReplyDeleteInu mi yoo dun ti e ba polongo re fun awon ti e jo n gbe tabi sise ki won wa wo ara ti a n da ati je igbadun Yoruba lakotun lori buloogu yii.
Ire loju owo n ri. Ire loju wa yoo ma ri o.
Ire!
Bee, a wa lori WhatsApp, e te nomba WhatsApp yin ranse, n o fi yin sinu egbe yii, OroYoruba ni, gbogbo ijiroro ati iforo-jomitoro-oro ti a n se nibe je ni ede Yoruba ponbele.
ReplyDelete