ÒDÍ MÉJÌ
.
Òdí méjì awo ilé Alárá
Òdí méjì awo ilé Ajerò
Àgbàlagbà Ifè
Ajífowó légbá Ajé tétété
Adía fún Òdí níjó tí Òdí mú Àjò pòn;
Òdí jóko ó fèhìn ti igi Akòko
Ó ní orò tó pò repete
Ibi a fi iyò sí ni iyò nsomi si
Ògèrèrè ire gbogbo ndà wá Ògèrèrè
.
Ká rí bátisà
Ká rí ònà gbegbà
No comments:
Post a Comment