18.9.16

AKANLO EDE

1.

Ṣé bí ojú ṣe rí nìyí, táa fi ńjobi lọ́jà Ẹdẹ? / Is this how things are that one gets to eat kolanut at Ede market?

[Used to react to a disappointing act.]

e.g. "Háà! Ayọ̀, irú ìwà wo lo hù yí? Ṣé bí ojú ṣe rí nìyí, táa fi ńjobi lọ́jà Ẹdẹ?" / " Arggh! Ayo, what have you done? Your action is disappointing to me."

No comments:

Post a Comment