
A dá búlọ́ọ̀gù yii sílẹ̀ látara ìpè níja tí a rí lórí íńtánẹ́ẹ̀tì bí kò ṣe si ẹyọ̀kan tí ó bójú tó èdè Yorùbá. Bẹ́ẹ̀ gbogbo ọmọ Kóòtû- ò-jíire ló mọ̀ pé ọrọ Yorùbá duǹ mọ̀rànyìn- mọranyin. Ní orí búlọ́ọ̀gù yìí, a o màa fi ìròyìn lẹ́kùn rẹ́rẹ́ tọ́ yín létí, òwe lọ́kan ò jọ̀kan ò ní gbẹ́yìn, àlọ́ àpamọ̀ àti àpagbè la ó máa fi dá ara wa lárará. Ẹ máa mìlíkì
18.9.16
OBA ALÁYÉ
OBA SALIU AKANMU ADETUNJI, Aje Ogungunniso 1
Kade pe lori, Baba Oluibadan tia.
Igba Yin Tintura...Ese Tebawa GbeAsa Yoruba Gaa....
Ede Naa Onipare o...Ilu Ibadan Konibaje o
oroyouba.blogspot.com.ng n fi towotowo ki Baba wa lori bi won se kan- an nipa laafin won pe ki ede Yoruba je kan ede kan soso ti won yoo maa so
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
No comments:
Post a Comment