19.9.16

ÌROYÌN

Oba Lateef Abayomi Dauda, Onitire ti Ilu Itire waja lowuro oni.

Ki Eledumare te won si afefe re.

A ba awon omo Ilu ati alabagbe ilu Itire kedun Oba won to lo.

No comments:

Post a Comment