A dá búlọ́ọ̀gù yii sílẹ̀ látara ìpè níja tí a rí lórí íńtánẹ́ẹ̀tì bí kò ṣe si ẹyọ̀kan tí ó bójú tó èdè Yorùbá. Bẹ́ẹ̀ gbogbo ọmọ Kóòtû- ò-jíire ló mọ̀ pé ọrọ Yorùbá duǹ mọ̀rànyìn- mọranyin. Ní orí búlọ́ọ̀gù yìí, a o màa fi ìròyìn lẹ́kùn rẹ́rẹ́ tọ́ yín létí, òwe lọ́kan ò jọ̀kan ò ní gbẹ́yìn, àlọ́ àpamọ̀ àti àpagbè la ó máa fi dá ara wa lárará. Ẹ máa mìlíkì
18.9.16
ORÍ MI ÀPÉ
Ori mi apere, ori mi apesin Ori laba bo. It is Ori that needs to be worshipped.
Ti a ba fi orisa sile. And not the deities
No Orisa can favour one without the consent of one’s Ori
It is Ori that aids one for one to be crowned of money
It is Ori that bless one for one to be using beaded walking stick even to the market
Ori, please, support me Ori, please, bless me Ori, please, never turn against me....
Ori mi jowo ma gba ibode ooo, Amin, Ase o. Ati Iwo Naa o.
- The Yorùbá Forum
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
No comments:
Post a Comment