9.9.16

Oruko Oye awon Oba Alaye ni Ile Yoruba (Apa Kinni)

Oruko oye awon Oba Alaye ni Ile Yoruba

Ipinle Oyo

1. Alaafin- Oyo
2. Olubadan- Ibadan
3. Soun- Ogbomoso
4. Okere- Saki
5. Eleruuwa- Eruwa
6. Onjo- Okeho
7. Olugbon- Igbon
8. Olu- Igbo-  Ora
9. Onikoyi- Ikoyi
10. Aseyin- Iseyin
11. Asigangan- Igangan
12. Sabiganna- Iganna
13. Oloko- Oko
14. Iba- Kisi

2 comments: