11.9.16

TALÓ MÒ Ó(ÌKÍNNÍ)?

Àló Àpamò 

Àlò baba mi kan láyé
Àlò baba mi kan làyè
 Owó níí je,
Kìí je àgbàdo
Kíni o o?

No comments:

Post a Comment