8.10.16

‎Adeola Adepoju‎ si IBADAN M'ESI O GO!(lati Facebook)

E ba mi gb'omo Oke.............Lanti lanti!!!!



Bi a ba se eni l'oore b'a o ba dupe, by olosa ko eni l'eru lo ma ni! Idi niyi ti mo se nke pe gbogbo Proudly Mesi o go ki e ba wa GBE ohun ope s'oke si okan ninu awon baba wa ninu egbe wa yii ti won fi awon ero ti a fi nye ifunpa wo ta egbe wa l'ore!

Gbara ti won gbo pe a o tun se eto ilera fun awon eeyan wa ni Ibadan l'osu to mbo ni won ti pe mi pe awon yoo fi ero tuntun meji ta wa l'ore.

Awon ero tuntun naa re e o. E ba mi s'adura fun won ki won o ma ri mu na, ri mu lo pelu idera.

Iru oore bayi ko yo enikeni ninu wa sole o, oke oke lowo wa yoo maa gbe o.

-Ìyá l'Áàfin Adéọlá Adépọ̀jù

No comments:

Post a Comment