ÀKANLÒ ÈDÈ APÁ KEJÌ
ÀKANLÒ ÈDÈ . ÌTUNMỌ̀
1. Ya akin . jẹ́ alágbára ènìyàn
2. Òkété bóru . ọ̀rọ̀ kọjá àtúnṣe
3. Ru etí ọmọ láńgidi . ṣe àìgbọràn
4. Mú ọ̀nà pọ̀n . tẹ̀ síwájú nínú ìrìn àjò
5. Na pápá bora . sálọ
6. Tu itọ́ sókè fi ojú gbà á . bínú gidigidi
7. Di bárakú . mọ́ ni lára
8. Fẹ́ra kù . lóyún
9. Ruga . hu ìwà ìgbéraga
10. Ológbò inú ọ̀kẹ́ . ohun tó dára níta tí kò dára nínú .
No comments:
Post a Comment