A dá búlọ́ọ̀gù yii sílẹ̀ látara ìpè níja tí a rí lórí íńtánẹ́ẹ̀tì bí kò ṣe si ẹyọ̀kan tí ó bójú tó èdè Yorùbá. Bẹ́ẹ̀ gbogbo ọmọ Kóòtû- ò-jíire ló mọ̀ pé ọrọ Yorùbá duǹ mọ̀rànyìn- mọranyin. Ní orí búlọ́ọ̀gù yìí, a o màa fi ìròyìn lẹ́kùn rẹ́rẹ́ tọ́ yín létí, òwe lọ́kan ò jọ̀kan ò ní gbẹ́yìn, àlọ́ àpamọ̀ àti àpagbè la ó máa fi dá ara wa lárará. Ẹ máa mìlíkì
21.10.16
ÌWÉ ÌTUNMỌ̀
ORÚKỌ ORÍKÌ
Àlàkẹ́ (o)- to take care of her as a result of victory over circumstance.
Ànìkẹ́ (o)- own's property to be taken care of.
Àbẹ̀ní (o)- begged for (from God or, more traditionally, the gods)
Àjàgbé (ọ) - fought to carry this child
Àkànní (ọ) - met only once to have this child
Àríkẹ̀ (o)- meant to be spoiled on sight
Àjọ́kẹ́ (o)- meant to be taken care of by all.
Àdùkẹ́ (o)- people will fight over the privilege to spoil her
Àbẹ̀bí (o)- begged for to be birthed (probably a difficult birth)
Àjàní (ọ)- fought to have this child
Àkànde (ọ) - favourite of the prince
Àkànní (ọ) - first male child
Àdìgún (ọ) - Name of God
Àpèkẹ́ (o) - Called to be cared for
Àdùnní (o) - One sweet to have
Àmọ̀kẹ́ (o) - Known and cared fori
Àjàdí(ọ) - the end of conflict
Àṣàkẹ́ (o)- selected to be spoiled (with good things)
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
No comments:
Post a Comment