2.10.16

ÌWÚRE

ÌWÚRE

Sekere kii rode ibanuje, oro ibanuje koni je temi.

Tijo-tayo ni ti sekere, oro ayo ati idunnu ko ni tan ninu ile mi.

Ogun idile ko ni bori mi.

Ki osu yii to pari, maa gbe ohun rere se

Oluwa gbami lowo ogun alaroka.

Aso ogo mi koni ya mo mi lorun.

Ijade ati iwole mi ko ni ja siku.

Eni eleni koni k’ere ise mi

(Ase).

No comments:

Post a Comment