28.10.16

ORIN

ORIN ÀJÙMỌ̀KỌ TI ILẸ̀ Ẹ O'ÒDUÀ

Isẹ́ wà fún ilẹ̀ wa
Fún orilẹ ìbí wa

K'agbégá k'agbégá k'agbégá f'áyérí
Ìgbagbo wa ni wipé b'áati b'ẹ́rú lab'ọ́mọ
.
Káṣiṣẹ́ káṣiṣẹ́ káṣiṣẹ́ kájọlà
Ìsọ̀kan àt'òmìnira ni k'ẹ́ẹjẹ ká máa lépaa
.
'Tẹsiwáju ọ̀pọ̀ ire at'ohun tó dáraa
Ọmọ Odu'a dide bọ́sí ipò ẹ̀tọ́ rẹ
Iwọ́ ní, imọ́lẹ́ gbogbo adúláwọ̀.
.
Ire ooo


oroyoruba.blogspot.com.ng

No comments:

Post a Comment