Òhun tí ajá rí tí ó gbó, kò tó èyí tí àgùntàn fi ṣe ìran wò.
Translation: What the dog sees and barks at does not amount to what the sheep sees and merely looks on.
Lílò: Èdè pé ohun tí ẹnì kan lè faradà, ẹlòmíràn lè ṣàìlè faradà tó bệ
Use: What some people can endure, others cannot.
No comments:
Post a Comment