A dá búlọ́ọ̀gù yii sílẹ̀ látara ìpè níja tí a rí lórí íńtánẹ́ẹ̀tì bí kò ṣe si ẹyọ̀kan tí ó bójú tó èdè Yorùbá. Bẹ́ẹ̀ gbogbo ọmọ Kóòtû- ò-jíire ló mọ̀ pé ọrọ Yorùbá duǹ mọ̀rànyìn- mọranyin.
Ní orí búlọ́ọ̀gù yìí, a o màa fi ìròyìn lẹ́kùn rẹ́rẹ́ tọ́ yín létí, òwe lọ́kan ò jọ̀kan ò ní gbẹ́yìn, àlọ́ àpamọ̀ àti àpagbè la ó máa fi dá ara wa lárará.
Ẹ máa mìlíkì
8.8.17
ORÍKÌ
Ede-odi (Mode Iresa)
omo bariola
egbeedogbon ikin
omo aguyan pupa
fun alejo pupa
oju n timi,oju n talejo mi
ojuntiyan,ojuntobelawo
iresa dudu legbon
pupa laburo
oju lo fin egbon
tofi we aburo mo
No comments:
Post a Comment