25.2.19

Ìwúrí

Quotable Quotes

A leader must not be afraid to fail; if he or she does, then he or she has failed to inspire a generation of great leaders in waiting. Failures are incubators that prepare leaders for greatness and embolden others to embrace larger than life endeavors.

- Akin Odumakinde

Àṣàyàn Ọ̀rọ̀ Kóríyá

Olórí kan ò gbọdọ̀ bẹ̀rù à ń ṣubú; bí ojora bá mú ú, ìgbà náà ló kùnà láti mú kóríyá bá ẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀rún aṣáájú pàtàki tí wọn n rosẹ̀ de ìgbà ti wọn. Ìṣubú jẹ́ àwọ̀n ìpẹ̀bí tí wọ́n ń se olórí gbogbo jiná fún ipò àgbà àti pé ó máa ń mú kóríyá bá àwọn ènìyàn láti gbé ohun ribiribi ayé ṣe

- Akin Òdúmákindé

Ọ̀rọ̀Yorùbá™
©2019

oroyoruba.blogspot.com.ng

No comments:

Post a Comment