8.5.22

EWI- WON N BA BABA SERE NI

WON N BA BABA SERE NI - Ayoola omo Fadeyi . Won n ba baba sere ni Ako aja won lo n gbo Kini won le se, ti baba o le se Won n ba baba sere ni . N o mo, bi ola yoo seri Sugbon, e je ki baba o de be Emi o se oselu esin Bee n o se oselu eleyameye Sugbon, ika to ba to loye ka fi romu . Omo le se bii baba looto Sebi baba rere ni i fe ki omo re laluyo Bee ni ti baba yii ri Sugbon, eyi ti baba nife si nisinsinyin Ko ba da, ki e gba baba laye Ki o le se iwon ti o le se Naijiria, mo gbagbo yoo gbadun re . Ire o! AyF™ ©2022

No comments:

Post a Comment