Èdè Yorùbá tí ó rẹwà
Ìṣsọ̀kan
Ìṣsọ̀kan dára,
Eje kí Ìṣsọ̀kan jọba láàrin wa,
Ibi tí Ìṣsọ̀kan bá wà,
Ìfẹ́, ayọ̀ ìdùnnú àti ifọkanbalẹ kò ní jina sí bẹ,
Eje ká ní Ìṣọ̀kan ni ìlú wa, agbègbè wa àti àdúgbò wa pẹ̀lú èyí Ìṣọ̀kan yoo le wà
láàrin àwa Yorùbá, Haúsá ibo
Àti gbogbo àwọn ẹ̀yà tí o so gbogbo orílẹ̀ èdè
Nàìjíríà papọ ni èyí tí yóò je ki agbe ìgbẹ́ ayò àti àlàáfíà laarin ara wa....
No comments:
Post a Comment