ÀKANLÒ ÈDÈ
APÁ KẸTA
1. Mú ọ̀nà pọ̀n . tẹ̀ síwájú nínú àjò
2. Na pápá bora . sálọ
3. Sọ ojú abẹ níkòó . sọ ohun tó jẹ́òtítọ́
4. Òkété bóru . ọ̀rọ̀ kọjá àtúnṣe
5. Lódìí ìgbín . dojú rú
6. Gbọ́nmi sí I, omi ò tó o . èdè àìyedè tàbí ìjà láàrí ín ẹni méjì
7. Fi ọ̀bọ lọ (ni) . fi ìwọ̀sí lọ ni
8. Ilẹ̀ ń mì . àṣírí fẹ́ tú
9. Já òwú dítí . ṣe àìgbọràn
10. Fi ìrù fọná . dá ọ̀ràn
No comments:
Post a Comment