22.10.16

ÀWỌN AKỌNI

SHEILA ṢOLARIN

Ìyàwó Ọ̀mọ̀we Táí Ṣolarin tí ó jẹ́ akínkanjú alátakò ìjọba àti ògbóǹtarìgì olùkọ́ ní ilẹ̀ Nàíjíríà.

Àná òde yìí ni ó pé ọdún mẹ́rin ti akínkanjú obìnrin yìí rèwàlẹ̀ àṣà.

Wọ́n kú ní Ọṣù Ọ̀wàrà, ọjọ kọkàn lé lógún, ọdun 2012 ni ilé rẹ̀ tí ó wà ní ọgbà ilé ẹ̀kọ́ Mayflower.



Sheila Obìnrin ogun, Sheila obìnrin rere

Ọmọ tó bí ju ẹgbẹ̀rún lọ, mi ò lè kà wọ́n tán ...

Màmá kò ì tó, kò ì tó o, ṣá ma kó wa nìṣó, a ó ṣọmọ fún ọ

1 comment:

  1. http://oroyoruba.blogspot.com/2016/10/itan-dowe_23.html

    ReplyDelete