17.4.17

ÒWE

Ẹni sọ̀rọ̀ púpọ̀, á ṣìsọ
.
Translation: One who talks much is likely to make mistakes
.
Lílò: Ìkìlọ̀ pé ó dára kí a yára gbọ́ ṣùgbọ́n kí a lọ́ra láti fèsì; nínú ísọ̀rọ̀ púpọ̀ ju bí ó ti yẹ ni a lè ká ọ̀rọ̀ mọ ‘ni lẹ́nu.
.
Use: We must be careful in our speech, especially in commenting upon the affairs of other people.

No comments:

Post a Comment